AFORITI LO LAYE
MOFE KI GBOGBO WA MO DAJUDAJUU
KI WURA TO DAN,OTI LANA KOJA
HUN BI ELEDUMARE LARO KADARA GBOGBO ENIYAN .
AFORITI NI ILA NI TIO FI KO
AFORITI NI AGBE NI OHUN OGBIN FITA
AFORITI LORO MO ADIE NI TIO FI DAKUKO
AFORITI KAN NAA NI IKAN NI TI O FI BAWON WEWE EJE.
RANTI PE AFORITI JAJU OHUN GBOGBO LO
AFORITI NI OMO IKOSE NI TI FI DOGA
AFORITI NI AKEEKO NI TO FI YEGE
RANTI TITA RIRO LAA KOLA
TOBA JINA TAN NI SOJU REKETE..
AFORITI NI ONISOWO NI TI AJE FI ILERE SE IBUGBE TI FI ODEDE RE SE AFIN
AFORITI LALA BARA MEJI NI TI FI RU ARUSO TI AFI PE NI IYA IBEJI
AFORITI NI LOGEDE NI TIO FI WO KOKO YE
AFORITI NI ORI NI TIO FI SE ATUKUN ARA
AFORITI NI AHUN TI FI SE ORE EYIN LADURU AGARA TO DA.
AFORITI NI EWURO NI TO FI JE AGBA IGI
AFORITI NI KAHUN NI TO FI JOBA LARIN EGBERUN OKUTA
AFORITI NI GBENI DE IPO OLA TI TU SONI DI ENI IYI LAWUJO
AFORITI NIMU OHUN GBOGBO SEREGI TIFI JORAWO.
1 comments:
Ewi: Aforiti ~ Asa-Tiwatiwa >>>>> Download Now
>>>>> Download Full
Ewi: Aforiti ~ Asa-Tiwatiwa >>>>> Download LINK
>>>>> Download Now
Ewi: Aforiti ~ Asa-Tiwatiwa >>>>> Download Full
>>>>> Download LINK
Post a Comment