Ewi:isokan
Isokan lokun
toso aye ro
Isokan lagba
ninu ohun gbogbo
Isokan koni
se nipa ile ti oti wa tabi eya ta tibi o
Okun ti kole
ja hunbi isokan ni
Apero isokan
ni ikan ni ti won fi mo ile
Apero isokan
ni erun ni ti won fi mo agiyan
Apero isokan
ni oyin ni ti won fi mo afara
Ewa eje kase
rawa losusu owo kase rawa lokan
Isokan lagba
ohun ni ife se arole fun
Isokan lobi
alaafia ti yoruba,igbo ati hausa nse gbe po ni ife aseitan
Isokan lomu ife
aseitan wa laarin loko laya
Hun bi ibi ti isokan ban gbe ibe ni ayo ohun alaafia
nbe
Hun bi ibi
isokan ba wa kosi gbekeyide nibe tutu niro koko lagba la hun bi isokan
Isokan lole
mu igbe aye gbadun fun gbogbo wa
Lagbaja pale
ogun mo lakasegbe gberin mo ote hun bi isokan lo sonu laarin won
Emaje ka
dalorun mo sapa,eje ki agba eri arawa je
Eje kasun
kale fedo lori ororo ki igbadun ledeba mutumuwa
Isokan lowa
larin isu to fi yoo omo ti ko gbagbe apari
Isokan
lagbado ni to fi yoo tie lai gba gbe irukere
Isokan kana
lowa larin omi ati iserun omi ti wo fi gbe po lalafia
(isokan lagba ri gbogbo
ebi oro)
1 comments:
Ewi: Isokan ~ Asa-Tiwatiwa >>>>> Download Now
>>>>> Download Full
Ewi: Isokan ~ Asa-Tiwatiwa >>>>> Download LINK
>>>>> Download Now
Ewi: Isokan ~ Asa-Tiwatiwa >>>>> Download Full
>>>>> Download LINK
Post a Comment