iku se ika,iku doro,iku mu eni ire lo
iku ogba owo
beni kogba obi tofi so ile ola di aworo
bi iku bada
ojo ni,bi o ba da osu laye omo adarinrun oba ti mura sile laye
iku oda ojo
beni koda osu to fi mu adetunji walo.
Ose, aise
igi toto ki bawo pe ni igbo
awon eni
rere ki bawo pe ni duniyan
gbigbo ti mo
gbo pe adeleke ku
odu mi omi
boloju mi,mo ni olore wa lo
akoni ninu
awon oselu pakoda.
Eni ajo ji
lowuro oni to tiwa dagbere faye pe odi igba ose
Ase igba tan
bi orere ojo bawo tan lobi opa ibon
Iku wole
logan loba mu baba walo
Ko gba owo
beni ko gba agbo iku seka
Se oti wa
tan nanu,se oti wa di o igbagbe na nu
Se otitu wa
di ohun itan na nu, pe erin subu,
pe ajanaku
si bi oke ,kole dide
serubawon
,odigbere, odi owuro,
Ipade tudi
ojuola,otu di ari nako
otu bawo di
oko alawo
otu di iwaju ite eledumare oba ni bi ti ipinya ko
ni si mo
odigba ooo
akoni okunrin,odigba gomina alagbada akoko ni pinle osun
oluomo odigba ose,gbogbo omo ede moku arogun se lede
leyin re
gbogbo re
omo se lede leyin re,gbogbo egbe olosusu owo se lede leyin re,
bobade ajule
mo bawo je ekolo moje ohun oti wo baje lajule orun ni ko mo bawo je.
Sunre ooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooo
1 comments:
Ewi: Idagbere Fun Senator Isiaka Adetunji Adeleke ~ Asa-Tiwatiwa >>>>> Download Now
>>>>> Download Full
Ewi: Idagbere Fun Senator Isiaka Adetunji Adeleke ~ Asa-Tiwatiwa >>>>> Download LINK
>>>>> Download Now
Ewi: Idagbere Fun Senator Isiaka Adetunji Adeleke ~ Asa-Tiwatiwa >>>>> Download Full
>>>>> Download LINK
Post a Comment