Ipinle osun
osun nje ilu
kekere kan ni iwo-orun gunsu ile nigeria,osun ti amenu le yii je yo lati inu
ilu lakan ti amosi ilu oyo ni odun 1989,oruko ti osun je,jeyo lati ara oruko
odo ti oyi ka ti amosi osun jela,odo ti aso nipa re yi tan ka gbogbo ilu osun
ti orirun odo na si wa ni osogbo olulu ipinle osun,won ma bo odo yi lodo dun,
oje odun kan gbogi ni ilu osun ti gbogbo omo osun ni ti ile toko ati awon are
lati oke-okun ni won ma pejo se odun na,ti odun osun si ti di ilu mo ka ni
gbogbo agbalaye .
Awon ilu
tinbe labe osun ni iwonyi
1
osogbo (olulu ipinle osun)
2 Ede
3 Ife (orirun ile yoruba)
4 Ikire
5 Ifon
6 ilobu
7 Iwo
8 Modakeke
8 Modakeke
9 Ilesa
10 Esa-oke
11 Ipetumodu
12 Ire
13 Ikirun
14 inisa
15 Okuku
16 Ode-omu
17 gbogan
18 Iba
19 oba
Ati bebe nlo
ni awon ilu naa
1 comments:
Itan Orile: Ilu Osun ~ Asa-Tiwatiwa >>>>> Download Now
>>>>> Download Full
Itan Orile: Ilu Osun ~ Asa-Tiwatiwa >>>>> Download LINK
>>>>> Download Now
Itan Orile: Ilu Osun ~ Asa-Tiwatiwa >>>>> Download Full
>>>>> Download LINK
Post a Comment